Abeni agbon biography of barack
Abeni agbon biography of barack
Biography of barack obama!
Iya Gbonkan: Ògbóǹtagì ojú tó ń dẹ́rù ba gbogbo ẹni tó ń wo fíìmù Yorùbá?
Oríṣun àwòrán, others
- Author, Yetunde Olugbenga
- Role, Senior Broadcast Journalist
Ni ọpọlọpọ ọdun sẹ́yìn, ṣe o leè pàdé oju oṣere yii ni ọganjọ oru koo ma bẹru?
Abi ṣe ẹ le pade iya naa ninu mọto tòun ti bi oju rẹ ṣe ri yii kẹ́ẹ ni "mama ṣe mo le baa yin ya "selfie"?
O n pa ni lẹrin bẹẹ ṣe n ka a yii amọ loju aye o le ma rẹrin rárá tori ọpọlọpọ ni yoo ti bẹru jina ki wọn to ranti pe oju aye la wa yii kii ṣe inu fiimu.
Ẹwẹ, lẹ́nu ọjọ mẹta yii, ẹ o ti maa ri oju Iya Gbonkan yii nita daadaa paapaa lori ayelujara, eyi si n túmọ̀ si pe aye ti n laju ti ọpọ oṣere si n fẹ́ ki awọn olólùfẹ́ wọn mọ pe eeyan ẹlẹ́ran ara bii tiwọn ni awọn naa n ṣe.
Ki ni ìbẹ̀rẹ̀ Iya Gbonkan?
Kii ṣe Iya Gbonkan ni baba ati iya to bi mama yii sọ ni kékeré, Margaret Mojoyinola Dele Olayinka gaan ni orúkọ oṣere yii amọ awọn eeyan o le gbagbọ ninu fiimu Yoruba pe ẹni ti wọn n ka